quarta-feira, 10 de setembro de 2025

Odu Okaran Oworin

 Odu Okaran Oworin




ESTUDAR É PRECISO

 

 

Bí Ifá lóò bá kọ́

Kóo kọ́fá

Kóo gbọ́fá ṣara ṣara bíi ará iwájú ṣe gbọ́fá

Bí èrù lóò bá jìjàdù

Kóo jìjàdù èrù bí ará ìgbàhun gbàhun

 

Ọmọ kékeré kìí jìjàdù èrù kó rí ìgúnlẹ̀ Ifá rere kọ́ wá sínú ilé

Ajadẹ Awo Ọlọ́fin

Dífá fún Ọlọ́fin ní kùtùkùtù òwúrọ̀

Ifá mọ́ jẹ̀ ẹ́ n rí ìjà aráyé

Ajadẹ

Ẹ̀là mọ́mọ̀ jẹ́ n ríjà

Ajadẹ

 

A óò tọ́jú pádi atare kan, a ó fi tẹ́lẹ̀ inú fìlà tí à ń dé sórí, a óò kó ọ̀pọ̀ ewé ajadẹ lé e lórí nínú fìlà náà. A ó gbe sínú agbada, a ó jo. A óò lọ́ kúnná dáadáa. A ó tẹ̀ẹ́, a ó pe Ifá síi. A ó ma fi fọ́ ẹ̀kọ tútù mu lọ́rọọrún.

 

TRADUÇÃO

 

 Se Ifá vai ensinar

 Não seja tímido.

 Não seja tão arrogante quanto a pessoa      da sua frente.

 Se for pesado, terá dificuldades.

 Não lute contra o medo como um tolo.

Uma criança pequena não luta contra o medo até que um bom espírito de Ifá entre em casa.

O Ajadê Awo Olofin

Orando a Deus de manhã cedo Ifá é aquele que vê a luta da humanidade.

 

Autor: Oluwo Ifagbaiyn Agbooola

Nenhum comentário:

Postar um comentário

Por que o Ifá é indicado para quem segue a Umbanda?

  Por que o Ifá é indicado para quem segue a Umbanda? Quando me pediram para escrever sobre a Umbanda e o Ifá, pensei muito antes de aceit...