Odu Okaran Oworin
ESTUDAR É
PRECISO
Bí Ifá lóò
bá kọ́
Kóo kọ́fá
Kóo gbọ́fá ṣara
ṣara bíi ará iwájú ṣe gbọ́fá
Bí èrù lóò
bá jìjàdù
Kóo jìjàdù
èrù bí ará ìgbàhun gbàhun
Ọmọ kékeré
kìí jìjàdù èrù kó rí ìgúnlẹ̀ Ifá rere kọ́ wá sínú ilé
Ajadẹ Awo Ọlọ́fin
Dífá fún Ọlọ́fin
ní kùtùkùtù òwúrọ̀
Ifá mọ́ jẹ̀ ẹ́
n rí ìjà aráyé
Ajadẹ
Ẹ̀là mọ́mọ̀
jẹ́ n ríjà
Ajadẹ
A óò tọ́jú
pádi atare kan, a ó fi tẹ́lẹ̀ inú fìlà tí à ń dé sórí, a óò kó ọ̀pọ̀ ewé ajadẹ
lé e lórí nínú fìlà náà. A ó gbe sínú agbada, a ó jo. A óò lọ́ kúnná dáadáa. A
ó tẹ̀ẹ́, a ó pe Ifá síi. A ó ma fi fọ́ ẹ̀kọ tútù mu lọ́rọọrún.
TRADUÇÃO
Se Ifá vai ensinar
Não seja tímido.
Não seja tão arrogante quanto a pessoa da sua frente.
Se for pesado, terá dificuldades.
Não lute contra o medo como um tolo.
Uma criança
pequena não luta contra o medo até que um bom espírito de Ifá entre em casa.
O Ajadê Awo
Olofin
Orando a
Deus de manhã cedo Ifá é aquele que vê a luta da humanidade.
Autor:
Oluwo Ifagbaiyn Agbooola